ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 April ojú ìwé 7
  • Máa Lo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́nà Tó Já Fáfá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Lo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́nà Tó Já Fáfá
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 April ojú ìwé 7

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Máa Lo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́nà Tó Já Fáfá

Wọ́n ń fi Bíbélì àti ìwé pẹlẹbẹ wàásù fún ọkùnrin kan

Ńṣe ni iṣẹ́ sísọni di ọmọ ẹ̀yìn dà bí ìgbà téèyàn bá ń kọ́lé. Kí ilé náà lè dúró digbí, a gbọ́dọ̀ mọ béèyàn ṣe ń lo àwọn ohun èlò ìkọ́lé dáadáa. Ó ṣe pàtàkì ká mọ bá a ṣe lè lo olórí ohun tá a fi ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́, ìyẹn Bíbélì, Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. (2Ti 2:15) A tún gbọ́dọ̀ mọ bá a ṣe lè lo àwọn ìwé àti fídíò tó wà lára Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà tó já fáfá, ká lè sọ àwọn èèyàn di ọmọlẹ́yìn.a

Báwo lo ṣe lè túbọ̀ mọ àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ lò dáadáa? (1) Ní kí alábòójútó àwùjọ yín ràn ẹ́ lọ́wọ́, (2) ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àkéde tó nírìírí tàbí aṣáájú-ọ̀nà déédéé, kó o sì (3) máa ṣe ìdánrawò déédéé. Tó o bá ti ń mọ àwọn ìwé àtàwọn fídíò yìí lò dáadáa, ayọ̀ rẹ á túbọ̀ máa kún bó o ṣe ń kópa nínú iṣẹ́ ìkọ́lé tẹ̀mí tó ń lọ lọ́wọ́ yìí.

ÌWÉ ÌRÒYÌN

Ilé Ìṣọ́
Jí!

ÌWÉ PẸLẸBẸ

Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
Àwọn Wo Ló Ń ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?
Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!

ÌWÉ ŃLÁ

Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run

ÀṢÀRÒ KÚKÚRÚ

Irú ìwé wo ni Bíbélì jẹ́?
Kí ló máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ ọ̀la?
Kí ló lè mú kí ìdílé láyọ̀?
Ta ló ń darí ayé yìí?
Ǹjẹ́ ìyà lè dópin?
Ǹjẹ́ àwọn òkú lè jíǹde?
Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?
Ibo la ti lè rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì nípa ìgbésí ayé?

FÍDÍÒ

Kí nìdí tó fi yẹ kó o kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?
Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?
 Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba?
Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

ÌWÉ ÌKÉSÍNI

Ìwé Ìkésíni sí Àwọn Ìpàdé Ìjọ

KÁÀDÌ ÌKÀNNÌ

Káàdì ìkànnì

a A dìídì ṣe àwọn ìtẹ̀jáde kan tí kò sí lárá Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn kan ní pàtàkì. A lè lo èyíkéyìí lára wọn nígbà tó bá yẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́