ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 1
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀ Màríà
Jèhófà yan Màríà pé kó ṣe iṣẹ́ pàtàkì kan tí kò tíì sí ẹni tó ṣe irú ẹ̀ rí, tí kò sì ní sí ẹni tó máa ṣe irú ẹ̀ torí pé ó ní ọkàn rere tó ṣàrà ọ̀tọ̀.
Báwo ni àwọn ọ̀rọ̀ tí Màríà sọ ṣe fi hàn pé ó ní . . .
ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀?
ìgbàgbọ́ tó lágbára?
ìmọ̀ Ìwé Mímọ́?
ìmọrírì fún Jèhófà?