ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 21-22
“Ìdáǹdè Yín Ń Sún Mọ́lé”
Jésù máa tó wá ṣèdájọ́ àwọn ẹni ibi, á sì gba àwọn olóòótọ́ là. A gbọ́dọ̀ múra sílẹ̀ nípa tẹ̀mí, ká bàa lè rí ìgbàlà.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.