Wọ́n ń kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba ní orílẹ̀-èdè Australia
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ibo làwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ ti lè rí ìrànlọ́wọ́?
Bíbélì: 2Kọ 1:3, 4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó bá kú?
○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó bá kú?
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìrètí wo ló wà fún àwọn tó ti kú?
○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Ìrètí wo ló wà fún àwọn tó ti kú?
Bíbélì: Iṣe 24:15
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ibo làwọn tó ti kú máa jíǹde sí?