Ètò ìrànwọ́ fáwọn tí àjálù dé bá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ló ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó ti kú?
Bíbélì: Onw 9:5a
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé ìrètí wà fún àwọn tó ti kú?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ṣé ìrètí wà fún àwọn tó ti kú?
Bíbélì: Job 14:14, 15
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá jí àwọn èèyàn wa tó ti kú dìde?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá jí àwọn èèyàn wa tó ti kú dìde?
Bíbélì: Ais 32:18
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa mú àlàáfíà wá sí ayé yìí?