ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 June ojú ìwé 2
  • “Àkàwé” Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Àkàwé” Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Ìṣàpẹẹrẹ” Tó Ṣe Pàtàkì Gan-an fún Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Majẹmu Ọlọrun Pẹlu “Ọ̀rẹ́” Rẹ̀ Ti Ṣanfaani fun Araadọta Ọkẹ Nisinsinyi
    Àìléwu Kárí-Ayé Labẹ “Ọmọ-Aládé Alaafia”
  • Ẹ̀yin Yóò Di “Ìjọba Àwọn Àlùfáà”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Ìbùkún Púpọ̀ Sí I Nípasẹ̀ Májẹ̀mú Tuntun
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 June ojú ìwé 2
Hágárì àti Sárà​—lọ́wọ́ ẹ̀yìn, wọ́n ń rúbọ nínú tẹ́ńpìlì; àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń wàásù; àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń gbọ́ bí wọ́n ṣe ń ka àkájọ ìwé

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | GÁLÁTÍÀ 4-6

“Àkàwé” Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀

4:​24-31

Pọ́ọ̀lù lo “àkàwé” yìí láti jẹ́ ká mọ̀ pé májẹ̀mú tuntun kì í ṣẹgbẹ́ májẹ̀mú Òfin. Lábẹ́ ìṣàkóso onífẹ̀ẹ́ Kristi àtàwọn tó máa bá a jọba, gbogbo aráyé máa gba òmìnira kúrò lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀, àìpé, ìbànújẹ́ àti ikú.​—Ais 25:​8, 9.

ẸRÚ NÁÀ HÁGÁRÌ

Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì lábẹ́ májẹ̀mú Òfin, Jerúsálẹ́mù sì ni olú ìlú rẹ̀

SÁRÀ​—OBÌNRIN TÓ LÓMÌNIRA

Jerúsálẹ́mù ti òkè, apá ti ọ̀run lára ètò Ọlọ́run

ÀWỌN “ỌMỌ” HÁGÁRÌ

Àwọn Júù (tó ṣèlérí pé àwọn á máa tẹ̀ lé májẹ̀mú Òfin) kọ Jésù, wọ́n sì pa á

ÀWỌN “ỌMỌ” SÁRÀ

Kristi àti àwọn Kristẹni tá a fẹ̀mí yàn tí iye wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì (144,000)

MÁJẸ̀MÚ ÒFIN TÓ MÚNI LẸ́RÚ

Òfin yẹn ló ń rán àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ ni wọ́n jẹ́

MÁJÈMÚ TUNTUN TÓ SỌNI DI ÒMÌNIRA

Ìgbàgbọ́ nínú ẹbọ ìràpadà Kristi máa dáni sílẹ̀ lọ́wọ́ ìdálẹ́bi Òfin, á sì sọni di òmìnira

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́