ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 July ojú ìwé 2
  • Ẹ Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀, Kí Ẹ sì Fi Ìwà Tuntun Wọ Ara Yín Láṣọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀, Kí Ẹ sì Fi Ìwà Tuntun Wọ Ara Yín Láṣọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • O Lè “Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Máa Fi “Ìwà Tuntun” Wọ Ara Rẹ Láṣọ Lẹ́yìn Tó O Ti Ṣèrìbọmi
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Irú Èèyàn Wo Lo Fẹ́ Jẹ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Bá A Ṣe Lè Gbé Àkópọ̀ Ìwà Tuntun Wọ̀, Tá Ò sì Ní Bọ́ Ọ Sílẹ̀ Mọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 July ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | KÓLÓSÈ 1-4

Ẹ Bọ́ Ìwà Àtijọ́ Sílẹ̀, Kí Ẹ sì Fi Ìwà Tuntun Wọ Ara Yín Láṣọ

3:5-14

Arábìnrin kan ń ṣàṣàrò lẹ́yìn tó ka ìwé Sún Mọ́ Jèhófà pẹ̀lú Bíbélì rẹ̀

Ṣé àwọn ìwà kan wà tó o máa ń hù tẹ́lẹ̀, tó o ti yí pa dà nígbà tó o di ìránṣẹ́ Jèhófà? Jẹ́ kó dá ẹ lójú pé inú Jèhófà dùn sí ohun tó o ṣe. (Isk 33:11) Àmọ́, ó gba pé kó o máa báa lọ láti máa sapá kí àwọn ìwà àtíjọ́ yẹn má bàa gbérí mọ́, kó o sì máa fi àwọn ìwà tuntun ṣèwà hù. Dáhùn àwọn ìbéèrè yìí, kó o lè rí àwọn ibi tó o ti lè sunwọ̀n sí i:

  • Ṣé mo ṣì ń bínú sí ẹnì kan tó ṣe nǹkan tó dùn mí?

  • Ṣé mo máa ń ṣe sùúrù, kódà nígbà tí mo bá ń kánjú tàbí tó bá rẹ̀ mí?

  • Tí èrò ìṣekúṣe bá wá sí mi lọ́kàn, ṣe kíá ni mo máa ń gbé e kúrò lọ́kàn?

  • Ṣé mo máa ń ro nǹkan tí kò dáa nípa àwọn tó wá láti ìlú míì tàbí orílẹ̀-èdè míì?

  • Ṣé mo bínú sí ẹnì kan lẹ́nu àìpẹ́ yìí àbí mo sọ̀rọ̀ burúkú sí i?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́