ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 July ojú ìwé 4
  • A Ó Fi Arúfin Náà Hàn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Ó Fi Arúfin Náà Hàn
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 July ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 TẸSALÓNÍKÀ 1-3

A Ó Fi Arúfin Náà Hàn

2:6-12

Kí ni Pọ́ọ̀lù ń tọ́ka sí nínú àwọn ẹsẹ yìí?

  • Àwọn Kristẹni apẹ̀yìndà wá da ìpàdé rú ní ọgọ́rùn-⁠ún ọdún kìíní

    “Ohun tó ń ṣèdíwọ́” (ẹsẹ 6)​—ó ṣeé ṣe kó jẹ́ àwọn àpọ́sítélì

  • “Fara hàn” (ẹsẹ 6)​—Lẹ́yìn ikú àwọn àpọ́sítélì, àwọn Kristẹni apẹ̀yìndà wá sójú táyé pẹ̀lú àgàbàgebè wọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn èèyàn ní àwọn ẹ̀kọ́ èké ní gbangba

  • “Àṣírí ìwà ìkà yìí” (ẹsẹ 7)​—Nígbà ayé Pọ́ọ̀lù, àwọn èèyàn ò mọ ẹni tí “arúfin náà” jẹ́

  • Àwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ń tako arákùnrin kan tó di Bíbélì mú

    “Arúfin náà” (ẹsẹ 8)​—Lónìí, òun ni gbogbo àwọn àlùfáà ṣọ́ọ̀ṣì

  • ‘Jésù Olúwa máa pa [arúfin náà] nígbà tó bá ṣe kedere pé ó ti wà níhìn-ín’ (ẹsẹ 8)​—Jésù máa jẹ́ kó ṣe kedere pé òun ni Ọba ní ọ̀run nígbà tó bá pa ètò nǹkan burúkú Sátánì yìí run, títí kan “arúfin náà”

Báwo ni ẹsẹ yìí ṣe fún ẹ níṣìírí láti máa fi ìtara wàásù, kó o sì gbà pé iṣẹ́ náà jẹ́ kánjúkánjú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́