ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 November ojú ìwé 8
  • Jèhófà Mọ Ohun Tá A Nílò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Mọ Ohun Tá A Nílò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Ń kó Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Aláyọ̀ Jọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • À Ń Fìfẹ́ Hàn Láwọn Àpéjọ Tá À Ń Ṣe Lọ́dọọdún
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àwọn Ìpàdé Tó Ń Fún “Wa Níṣìírí Láti Ní Ìfẹ́ àti Láti Ṣe Àwọn Iṣẹ́ Rere”
    A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
  • Bí A Ṣe Ń Pàdé Pọ̀ Láti Jọ́sìn
    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 November ojú ìwé 8
Àwọn arábìnrin ń pàtẹ́wọ́ nígbà àpéjọ agbègbè kan

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Mọ Ohun Tá A Nílò

Ẹrú olóòótọ́ àti olóye ń pèsè oúnjẹ tẹ̀mí fún wa “ní àkókò tó yẹ,” èyí sì fi hàn pé Jèhófà, ẹni tó ń darí ẹrú náà mọ ohun tá a nílò nípa tẹ̀mí. (Mt 24:45) Àwọn àpéjọ agbègbè àtàwọn ìpàdé àárín ọ̀sẹ̀ tá à ń gbádùn fi hàn pé Jèhófà ń pèsè ohun tá a nílò lóòótọ́.

WO FÍDÍÒ NÁÀ ÌRÒYÌN IṢẸ́ ÌGBÌMỌ̀ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́​—2017, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwọn tó wá sí àpéjọ agbègbè kún inú pápá ìṣeré kan

    Ta ni ọpẹ́ àti ìyìn yẹ fáwọn àpéjọ agbègbè tó bọ́ sákòókò tá à ń gbádùn, kí sì nìdí?

  • Ìgbà wo ni iṣẹ́ máa ń bẹ̀rẹ̀ lórí àpéjọ agbègbè wa?

  • Ẹgbẹ́ Àwọn Tó Ń Ṣe Fídíò ń ṣe fídíò kan tí wọ́n máa wò nígbà àpéjọ agbègbè

    Báwo la ṣe máa ń yan àwọn àkòrí àpéjọ agbègbè wa?

  • Àwọn iṣẹ́ wo la máa ń ṣe láti ṣètò àpéjọ agbègbè kan?

  • Báwo ni wọ́n ṣe ṣètò ìpàdé ààrín ọ̀sẹ̀ kó lè dà bí ọ̀nà tí wọ́n gbà ń kẹ́kọ̀ọ́ ní Gílíádì?

  • Arákùnrin kan mú ìwé ìpàdé dání

    Báwo ni onírúurú ẹ̀ka ṣe ń ṣiṣẹ́ pa pọ̀ láti ṣe ìwé ìpàdé?

Báwo làwọn nǹkan tẹ̀mí tí Jèhófà fún wa ṣe rí lára rẹ?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́