ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
  • ○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 1
Àwọn arábìnrin kan ń fi fóònù wàásù níbi térò pọ̀ sí ní Switzerland

Àwọn arábìnrin kan ń fi ọ̀kan lára àwọn fídíò tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ wàásù ní Switzerland

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ibo la ti lè rí ìmọ̀ràn tó dáa jù lọ nípa bá a ṣe lè láyọ̀?

Bíbélì: Sm 1:1, 2

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Tẹ́nì kan bá nífẹ̀ẹ́ owó jù, àkóbá wo nìyẹn lè ṣe fún un?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Tẹ́nì kan bá nífẹ̀ẹ́ owó jù, àkóbá wo nìyẹn lè ṣe fún un?

Bíbélì: 1Ti 6:9, 10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí kò fi dáa kéèyàn máa ronú jù nípa àwọn ìṣòro tó ní?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí nìdí tí kò fi dáa kéèyàn máa ronú jù nípa àwọn ìṣòro tó ní?

Bíbélì: Owe 17:22

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ìdílé kan ṣe lè láyọ̀ láìka àwọn ìṣòro wọn sí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́