ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 1
Àwọn àlùfáà ń ṣiṣẹ́ nínú àgbàlá àgọ́ ìjọsìn nítòsí bàsíà bàbà àti níbi pẹpẹ ẹbọ sísun. Àlùfáà kan dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ tábìlì búrẹ́dì àfihàn tó wà nínú Ibi Mímọ́.

Àwọn àlùfáà ń ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìjọsìn

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ibo la ti lè rí ìmọ̀ràn tó dáa jù nípa bá a ṣe lè láyọ̀?

Bíbélì: Sm 1:1, 2

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣéèyàn máa láyọ̀ tó bá nífẹ̀ẹ́ owó, tó sì ní ohun ìní tó pọ̀?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!’

    fg ẹ̀kọ́ 12 ¶6

○● ÌPADÀBẸ̀WÒ

Ìbéèrè: Ṣéèyàn máa láyọ̀ tó bá nífẹ̀ẹ́ owó, tó sì ní ohun ìní tó pọ̀?

Bíbélì: 1Ti 6:9, 10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àǹfààní wo ló wà nínú kéèyàn gbà pé nǹkan ṣì máa dáa?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!’

    fg ẹ̀kọ́ 11 ¶7

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́