ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 2
  • “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀rí Tó Ta Yọ Jù Lọ Pé Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Sọ Pé Kí Ábúráhámù Fi Ọmọ Rẹ̀ Rúbọ?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ọlọ́run Dán Ìgbàgbọ́ Ábúráhámù Wò
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ọlọ́run Dán Ìgbàgbọ́ Ábúráhámù Wò
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 22-23

“Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò”

22:1, 2, 9-12, 15-18

Ẹ̀dùn ọkàn tí Ábúráhámù ní nígbà tó fẹ́ fi Ísákì rúbọ jẹ́ ká mọ bí nǹkan ṣe máa rí lára Jèhófà nígbà tó fi Jésù Kristi, Ọmọ Rẹ̀ ọ̀wọ́n rúbọ nítorí wa. (Jo 3:16) Báwo ni ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ ní ẹsẹ 2 ṣe jẹ́ ká mọ bó ṣe nífẹ̀ẹ́ Jésù tó?

Àwòràn: 1. Ábúráhámù mú ọ̀bẹ dání, ó ń wòkè nígbà tí Ísákì dùbúlẹ̀ lórí pẹpẹ. 2. Wọ́n gbé Jésù kọ́ sórí òpó igi oró.

Kí ló yẹ kí ìfẹ́ tí Jèhófà ní sún ẹ láti ṣe?​—1Kọ 6:20; 1Jo 4:11

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́