ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 March ojú ìwé 4
  • Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Ìpinnu Tó Dára Kó O Má Bàa Pàdánù Ogún Tẹ̀mí Rẹ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Jékọ́bù Rí Ogún Gbà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Máa Ń Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 March ojú ìwé 4
Arákùnrin kan ń ṣàṣàrò lórí ohun tó kà látinú Bíbélì. Ó ń fọkàn yàwòrán bí Ísọ̀ ṣe ta ogún ìbí rẹ̀ fún Jékọ́bù torí abọ́ ọbẹ̀ ẹ̀wà lẹ́ńtìlì kan ṣoṣo.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 25-26

Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀

25:27-34

Ísọ̀ “kò mọyì àwọn ohun mímọ́.” (Heb 12:16) Ìdí nìyẹn tó fi ta ogún ìbí rẹ̀, tó sì tún fẹ́ àwọn obìnrin tí kò sin Jèhófà.​—Jẹ 26:34, 35.

BI ARA RẸ PÉ: ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo mọyì àwọn ohun mímọ́ yìí?’

  • Àjọṣe mi pẹ̀lú Jèhófà

  • Ẹ̀mí mímọ́

  • Bá a ṣe ń jẹ́ orúkọ mọ́ Jèhófà

  • Iṣẹ́ ìwàásù

  • Àwọn ìpàdé wa

  • Ìgbéyàwó

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́