ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 8
  • Kí Ló Ṣe Pàtàkì Jù Sí Mi?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ló Ṣe Pàtàkì Jù Sí Mi?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Ìjọsìn Jèhófà Ló Gbawájú ní Ìgbésí Ayé Yín?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Ìgbà Wo Ni Jèhófà Máa Ń Bù Kún—Ìsapá Tí A Fi Taratara Ṣe?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Fi Àwọn Ohun Tó Ò Ń lé Nípa Tẹ̀mí Yin Ẹlẹ́dàá Rẹ Lógo
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Báwo Ni Ọwọ́ Mi Ṣe Lè Tẹ Àwọn Àfojúsùn Mi?
    Jí!—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 8
Jékọ́bù ń bá áńgẹ́lì kan jìjàkadì.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kí Ló Ṣe Pàtàkì Jù Sí Mi?

Jékọ́bù bá áńgẹ́lì jìjàkadì torí kó lè gba ohun kan tó ṣe pàtàkì gan-an, ìyẹn ìbùkún Jèhófà. (Jẹ 32:24-31; Ho 12:3, 4) Àwa ńkọ́? Ṣé a ṣe tán láti fi gbogbo okun àti agbára wa ṣègbọràn sí Jèhófà, ká lè gba ìbùkún rẹ̀? Bí àpẹẹrẹ, tí àsìkò ìpàdé bá forígbárí pẹ̀lú àsìkò tá a lè ṣe àfikún iṣẹ́, èwo la máa ṣe? Tá a bá ń lo àkókò wa, okun wa àtàwọn ohun ìní wa fún Jèhófà, ó máa ‘tú ìbùkún sórí wa títí a kò fi ní ṣaláìní ohunkóhun.’ (Mal 3:10) Á máa tọ́ wa sọ́nà, á máa dáàbò bò wá, á sì máa pèsè gbogbo ohun tá a nílò.​—Mt 6:33; Heb 13:5.

WO FÍDÍÒ NÁÀ JẸ́ KÍ ÀWỌN ÀFOJÚSÙN TẸ̀MÍ WÀ LỌ́KÀN RẸ DIGBÍ, KÓ O SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Arábìnrin aṣáájú ọ̀nà kan tó ń ṣiṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ níbi tí wọ́n ti ń túmọ̀ èdè àwọn adití.

    Báwo ni ohun tí arábìnrin yìí fẹ́ràn ṣe di ìdẹwò fún un?

  • Arábìnrin náà ń ṣiṣẹ́ dalẹ́ ní ọ́fí ìsì rẹ̀.

    Báwo ni iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ wa ṣe lè di ìdẹwò fún wa?

  • Tímótì dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ wíńdò kan, ó sì ń ka àkájọ ìwé kan lálẹ́.

    Kí nìdí tó fi yẹ kí Tímótì máa ní àfojúsùn tẹ̀mí kódà lẹ́yìn tí òtítọ́ ti jinlẹ̀ nínú rẹ̀?​—1Ti 4:16

  • Arábìnrin aṣáájú ọ̀nà yìí àti arábìnrin míì ń kí akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan bí wọ́n ṣe ń dé láti wá ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀.

    Kí ló ṣe pàtàkì jù nígbèésí ayé rẹ?

    Báwo la ṣe lè fi hàn pé iṣẹ́ Ọlọ́run la kà sí pàtàkì jù?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́