ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 July ojú ìwé 2
  • “Ní Báyìí, Wàá Rí Ohun Tí Màá Ṣe sí Fáráò”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ní Báyìí, Wàá Rí Ohun Tí Màá Ṣe sí Fáráò”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ta Ni Jehofa?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Ọba Búburú Kan Jẹ Ní Íjíbítì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • ‘Jáà Ni Ìgbàlà Mi’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Líla Òkun Pupa Kọjá
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 July ojú ìwé 2
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti ọ̀pọ̀ àwọn tí kì í ṣe ọmọ Ísírẹ́lì jọ jáde kúrò ní Íjíbítì.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 6-7

“Ní Báyìí, Wàá Rí Ohun Tí Màá Ṣe sí Fáráò”

6:1, 6, 7; 7:4, 5

Kó tó di pé Jèhófà mú ìyọnu mẹ́wàá wá sórí àwọn ará Íjíbítì, tó sì gba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀, ó jẹ́ káwọn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mọ ohun tí òun máa ṣe. Wọ́n máa rí ọwọ́ agbára Jèhófà lọ́nà tí wọn ò rírú ẹ̀ rí, àwọn ará Íjíbítì sì máa mọ irú ẹni tí Jèhófà jẹ́. Nígbà táwọn ìlérí Jèhófà ṣẹ, ìgbàgbọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì túbọ̀ lágbára sí i, ìyẹn sì mú kí wọ́n jáwọ́ nínú ìbọ̀rìṣà tí wọ́n tí ń lọ́wọ́ sí tẹ́lẹ̀ ní Íjíbítì.

Báwo ni ìtàn Bíbélì yìí ṣe jẹ́ kó dá ẹ lójú pé àwọn ìlérí Jèhófà máa ṣẹ?

Àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà tó jẹ́ olóòótọ́ la ìpọ́njú ńlá já.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́