ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 July ojú ìwé 4
  • Mósè àti Áárónì Lo Ìgboyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Mósè àti Áárónì Lo Ìgboyà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Mose àti Aaroni—Àwọn Onígboyà Olùpòkìkí Ọ̀rọ̀ Ọlọrun
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Mósè Àti Áárónì Lọ Rí Fáráò
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Ǹjẹ́ Ò Ń Rí “Ẹni Tí A Kò Lè Rí”?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 July ojú ìwé 4
Mósè àti Áárónì dúró níwájú Fáráò, Fáráò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 10-11

Mósè àti Áárónì Lo Ìgboyà

10:3-6, 24-26, 28; 11:4-8

Mósè àti Áárónì fi hàn pé àwọn nígboyà, wọn ò sì bẹ̀rù nígbà tí wọ́n kojú Fáráò, ìyẹn ẹni tó lágbára jù lọ láyé nígbà yẹn. Kí ló ràn wọ́n lọ́wọ́? Bíbélì sọ nípa Mósè pé: “Ìgbàgbọ́ mú kó kúrò ní Íjíbítì, àmọ́ kò bẹ̀rù ìbínú ọba, torí ó dúró ṣinṣin bíi pé ó ń rí Ẹni tí a kò lè rí.” (Heb 11:27) Mósè àti Áárónì nígbàgbọ́ tó lágbára nínú Jèhófà, wọ́n sì gbẹ́kẹ̀ lé e.

Àwọn ipò wo lo ti nílò ìgboyà láti sọ ohun tó o gbà gbọ́ fún ẹnì kan tó wà nípò àṣẹ?

Àwòrán: Àwọn ipò tá a ti lè fi ìgboyà hàn. 1. Ọmọ kan níléèwé dúró jẹ́ẹ́ nígbà táwọn yòókù ń kí àsíá. 2. Arákùnrin kan dúró nílé ẹjọ́. 3. Arákùnrin kan ń fún ẹnì kan ní àṣàrò kúkúrú, àwọn ọlọ́pàá tó wà nítòsí ń wò wọ́n.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́