ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 2
  • A Gbọ́dọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ju Ìdílé Wa Lọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Gbọ́dọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ju Ìdílé Wa Lọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọwọ́ Tó Yẹ Ká Fi Mú Ẹni Tí Wọ́n Bá Yọ Lẹ́gbẹ́
    ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Fi Ìdúróṣinṣin Kristẹni Hàn Nígbà Tí Ìbátan Rẹ Kan Bá Di Ẹni Tí A Yọ Lẹ́gbẹ́
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2002
  • O Lè Jẹ́ Olóòótọ́ Tí Èèyàn Ẹ Kan Bá Fi Jèhófà Sílẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 2
Áárónì Àlùfáà Àgbà dúró ní àgbàlá àgọ́ ìjọsìn. Méjì lára àwọn mọ̀lẹ́bí Áárónì gbé òkú Nádábù àti Ábíhù jáde kúrò nínú ibùdó.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 10-11

A Gbọ́dọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ju Ìdílé Wa Lọ

10:1, 2, 4-7

Nádábù àti Ábíhù gbé ìkóná tí wọ́n fi ń sun tùràrí dání.

Tí wọ́n bá yọ èèyàn wa kan lẹ́gbẹ́, ó lè nira fún wa láti pinnu ẹni tó yẹ ká jẹ́ adúróṣinṣin sí. Ìtọ́ni tí Jèhófà fún Áárónì jẹ́ ká rí i pé a gbọ́dọ̀ yẹra fún mọ̀lẹ́bí wa tí wọ́n yọ lẹ́gbẹ́. Ìfẹ́ tá a ní fún Jèhófà gbọ́dọ̀ lágbára ju ìfẹ́ tá a ní fún mọ̀lẹ́bí wa tó jẹ́ aláìṣòótọ́.

Àwọn ìbùkún wo la máa rí tá a bá ń tẹ̀ lé ìtọ́ni tí Jèhófà fún wa nípa bó sẹ yẹ ká máa ṣe sáwọn tí wọ́n yọ lẹ́gbẹ́?​—1Kọ 5:11; 2Jo 10, 11

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́