ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 4
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Òfin Nípa Àrùn Ẹ̀tẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Òfin Nípa Àrùn Ẹ̀tẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìgbésí Ayé Mi Gẹ́gẹ́ Bí Adẹ́tẹ̀—Mo Láyọ̀, A Sì Bù Kún Mi Nípa Tẹ̀mí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
  • Ǹjẹ́ O Mọ̀?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ìyọ́nú fun Adẹ́tẹ̀ Kan
    Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 12-13

Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Òfin Nípa Àrùn Ẹ̀tẹ̀

13:4, 5, 45, 46, 52, 57

Tá a bá ronú lórí ìdí tí Jèhófà fi fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lófin nípa àrùn ẹ̀tẹ̀, báwo nìyẹn ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ kí àjọṣe wa pẹ̀lú Jèhófà túbọ̀ lágbára?

  • Jèhófà jẹ́ kí àwọn àlùfáà mọ bí wọ́n ṣe lè tètè dá àrùn ẹ̀tẹ̀ mọ̀. Lónìí, àwọn alàgbà gbọ́dọ̀ wà lójúfò kí wọ́n lè tètè mọ̀ tí ẹnì kan bá nílò ìrànlọ́wọ́ nípa tẹ̀mí.​—Jem 5:14, 15

  • Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́dọ̀ dáná sun ohunkóhun tí àrùn náà bá wà lára ẹ̀ kó má bàa ran àwọn míì. Àwa Kristẹni náà gbọ́dọ̀ ṣe tán láti yááfì àwọn ohun tá a nífẹ̀ẹ́ sí dípò ká jẹ́ kí wọ́n sún wa dẹ́sẹ̀. (Mt 18:8, 9) Ó lè jẹ́ àwọn àṣà tó ti mọ́ wa lára, àwọn ọ̀rẹ́ wa tàbí eré ìnàjú

Obìnrin kan pinnu pé òun ò ní mu ọtí àmujù mọ́, ó sì dúró lórí ìpinnu rẹ̀.

Báwo ni Kristẹni kan ṣe lè fi hàn pé òun fẹ́ kí Jèhófà ran òun lọ́wọ́?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́