ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 5
  • Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà Ní Mímọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà Ní Mímọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • A Wẹ̀ Wá Mọ́ Láti Jẹ́ Èèyàn Fún Iṣẹ́ Àtàtà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn Tó Mọ́ Tónítóní
    ‘Ẹ Dúró Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run’
  • Àwọn Ìránṣẹ́ Ọlọrun Gbọ́dọ̀ Mọ́ Tónítóní
    Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
  • Ìmọ́tótó
    Jí!—2015
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 14-15

Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà ní Mímọ́

15:13-15, 28-31

Ká tó lè dúró nínú ìfẹ́ Ọlọ́run, a gbọ́dọ̀ wà ní mímọ́ nínú èrò àti ìṣe wa. Èyí túmọ̀ sí pé a gbọ́dọ̀ máa tẹ̀ lé àwọn ìtọ́ni Jèhófà tó bá dọ̀rọ̀ ìmọ́tótó nípa tara, nípa tẹ̀mí àti nínú ìwà wa, láìka pé àwọn èèyàn ò fọwọ́ pàtàkì mú ọ̀rọ̀ yìí. Ó yẹ ká yẹra fún ohunkóhun tí Baba wa ọ̀run kà sí àìmọ́.

Àwòrán: Àwòrán tó ṣàlàyé oríṣiríṣi ìwà àìmọ́ táwọn èèyàn ń hù lónìí. 1. Aṣáájú ìsìn kan ń gbàdúrà fún àwọn ọmọ ogun. 2. Obìnrin aṣáájú ìsìn kan ń so ọkùnrin méjì pọ̀ di tọkọtaya. 3. Wọ́n pàtẹ àwòrán ibi tí wọ́n bí Jésù sí ní ibùjẹ ẹran àti igi Kérésìmesì ní ilé ìtajà kan.

Àǹfààní wo ni máa rí tí mo bá sá fún ohun àìmọ́ inú ayé yìí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́