ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 6
  • Fi Jèhófà Ṣe Ibi Ààbò Rẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Fi Jèhófà Ṣe Ibi Ààbò Rẹ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àwọn Ìlú Ààbò—Ìpèsè Aláàánú Ọlọrun
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • Ṣé Ò Ń Sá Di Jèhófà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • “Gbé Ọmọ Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Fi Jèhófà Ṣe Ibi Ààbò Rẹ

Jèhófà ní káwọn ọmọ Ísírẹ́lì yan ìlú mẹ́fà tó máa jẹ́ ìlú ààbò, kí ẹnikẹ́ni tó bá ṣèèṣì pààyàn lè sá lọ síbẹ̀ (Nọ 35:15; w17.11 9 ¶4)

Àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì ló máa dá ẹjọ́ yìí (Nọ 35:24; w17.11 9 ¶6)

Tẹ́ni tó ṣèèṣì pààyàn bá ti wà nílùú ààbò, kò sóhun tó máa ṣẹlẹ̀ sí i (Nọ 35:25; w17.11 11 ¶13)

Bó ṣe jẹ́ pé ẹni tó ṣèèṣì pààyàn máa ní láti fi ọ̀pọ̀ nǹkan sílẹ̀ kó tó lè lọ sílùú ààbò, kó sì máa gbébẹ̀ láìséwu, àwa náà ti yááfì ọ̀pọ̀ nǹkan ká lè máa gbádùn àánú Ọlọ́run àti ìdáríjì rẹ̀.

Inú ọ̀dọ́kùnrin kan bà jẹ́. Àwòrán: Wọ́n ń bẹ Jèhófà pé kó dárí ji àwọn. 1. Ọmọ Ísírẹ́lì kan ṣe ohun tí ò dáa, ó ronú pìwà dà, ó sì ń sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ fáwọn àgbààgbà lẹ́nu ibodè ìlú. 2. Ọ̀dọ́kùnrin tínú ẹ̀ bà jẹ́ yẹn lọ bá àwọn alàgbà torí pé ó ṣe ohun tí ò dáa.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́