ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 16
  • Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Lórí Ọ̀rọ̀ Ọtí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Lórí Ọ̀rọ̀ Ọtí
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìwọ Ha Ní Ojú Ìwòye Ọlọ́run Nípa Ọtí Líle Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Ṣó Burú Kéèyàn Máa Mutí Líle?
    Jí!—2007
  • Ṣó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Mu Ọtí?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Ṣọ́ra Fún Ọtí Àmujù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 16

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Lórí Ọ̀rọ̀ Ọtí

Àwòrán látinú fídíò ‘Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọtí Di Ìdẹkùn fún Ẹ.’ Ejò eléyín méjì yọ látinú ọtí tí ọkùnrin kan gbé dání.

Gbogbo àwa Kristẹni la gbọ́dọ̀ máa kó ara wa níjàánu tó bá dọ̀rọ̀ ká mutí. (Owe 23:20, 29-35; 1Kọ 6:9, 10) Tí Kristẹni kan bá pinnu láti mutí, ó gbọ́dọ̀ mu ún níwọ̀ntúnwọ̀nsì. Ó tún gbọ́dọ̀ ṣọ́ra kí ọtí má bàa di bárakú fún un, kó má sì mú àwọn míì kọsẹ̀. (1Kọ 10:23, 24; 1Ti 5:23) Bákan náà, kò yẹ ká máa ti àwọn míì láti mutí, pàápàá jù lọ àwọn ọ̀dọ́.

Ẹ WO FÍDÍÒ ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ NÁÀ MÁ ṢE JẸ́ KÍ ỌTÍ DI ÌDẸKÙN FÚN Ẹ, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Kí nìdí tó fi yẹ káwa Kristẹni máa pa òfin ìjọba mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ọtí mímu?​—Ro 13:1-4

  • Kí nìdí tí kò fi yẹ ká jẹ́ káwọn míì tì wá láti mutí?​—Ro 6:16

  • Kí la lè ṣe láti yẹra fún ewu tó ní ín ṣe pẹ̀lú ọtí mímu?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́