ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 12
  • “Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ohun Tí Àpèjúwe Tó Wà Nínú Orin Onímìísí Kan Kọ́ Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 12
Nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ìdílé kan jókòó sábẹ́ igi níwájú ilé wọn, inú wọn ń dùn bí wọ́n ṣe jọ ń sọ̀rọ̀. Àwọn àgùntàn sì ń jẹko nítòsí wọn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”

Àwọn tó ṣègbọràn sí Jèhófà rí ọ̀pọ̀ ìbùkún (Di 28:1, 3-6; w10 12/15 19 ¶18)

Ìbùkún tó pọ̀ yanturu ni Jèhófà máa fún àwọn tó bá ń ṣègbọràn sí i (Di 28:2; w01 9/15 10 ¶2)

Jèhófà fẹ́ ká máa “fi ìdùnnú àti ayọ̀ tó wá látọkàn” ṣègbọràn sí òun (Di 28:45-47; w10 9/15 8 ¶4)

Àwọn ará lọ́kùnrin lóbìnrin tí ẹ̀yà wọn yàtọ̀ síra ń jẹun pa pọ̀ lẹ́yìn ìpàdé agbègbè.

Àwọn tó ń ṣègbọràn sí Jèhófà ń rí ọ̀pọ̀ ìbùkún báyìí, Jèhófà tún ṣèlérí pé wọ́n máa rí ìbùkún tó pọ̀ gan-an lọ́jọ́ ìwájú.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́