ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 May ojú ìwé 8
  • Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbára Lé Jèhófà fún Ìrànlọ́wọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • “Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 May ojú ìwé 8
Ọba Dáfídì ń wo ìta látojú fèrèsé ààfin rẹ̀.

Dáfídì ń ronú lórí májẹ̀mú tí Jèhófà dá pẹ̀lú rẹ̀

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú

Jèhófà ṣèlérí fún Dáfídì pé òun máa fìdí ìjọba rẹ̀ àti ti àtọmọdọ́mọ rẹ̀ múlẹ̀ (2Sa 7:11, 12, àlàyé ìsàlẹ̀; w10 4/1 20 ¶3; wo àwòrán iwájú ìwé)

Àwọn apá kan lára májẹ̀mú tí Jèhófà bá Dáfídì dá ṣẹ sí Mèsáyà lára (2Sa 7:13, 14; Heb 1:5; w10 4/1 20 ¶4)

Títí láé la máa gbádùn àwọn ìbùkún tí Ìjọba Mèsáyà máa mú wá (2Sa 7:15, 16; Heb 1:8; w14 10/15 10 ¶14)

Jésù ń wo ayé láti ìtẹ́ rẹ̀ lọ́run.

Bó ṣe dá wa lójú pé kò sóhun tó lè mú kí oòrùn àti òṣùpá má yọ, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe dá wa lójú pé ìṣàkóso Mèsáyà máa wà títí láé. (Sm 89:35-37) Torí náà tó o bá ti ń rí oòrùn àti òṣùpá, máa ronú nípa ìlérí tí Jèhófà ṣe pé Ìjọba òun máa mú ìbùkún wá fún ìwọ àti ìdílé rẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́