ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 13
  • Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jason Worilds: Èèyàn Ò Lè Pàdánù Ohunkóhun Tó Bá Fayé Ẹ̀ Sin Jèhófà
    Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà
  • Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Èé Ṣe Tí Mo Fi Ń Ṣàìsàn Tó Bẹ́ẹ̀?
    Jí!—1997
  • Ábúráhámù Jẹ́ Ẹni Tó Ní Ìgbàgbọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 13

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo

Ó lè má rọrùn láti fi Ìjọba Ọlọ́run àti òdodo rẹ̀ sípò àkọ́kọ́ láyé wa tí àtijẹ-àtimu bá ṣòro. Ó lè máa ṣe wá bíi pé ká gba iṣẹ́ tó ta ko àwọn ìlànà Bíbélì tàbí èyí tí ò ní jẹ́ ká ráyè sin Jèhófà. Àmọ́, ẹ jẹ́ kó dá wa lójú pé Jèhófà máa ń fi agbára rẹ̀ hàn “nítorí àwọn tí wọ́n ń fi gbogbo ọkàn wọn sìn ín.” (2Kr 16:9) Kò sóhun tó lè dí Baba wa onífẹ̀ẹ́ lọ́wọ́ láti pèsè àwọn nǹkan tá a nílò àti láti ràn wá lọ́wọ́. (Ro 8:32) Torí náà, tá a bá fẹ́ pinnu irú iṣẹ́ tá a máa ṣe, ó ṣe pàtàkì ká gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, ká sì pọkàn pọ̀ sórí iṣẹ́ ìsìn wa sí i.​—Sm 16:8.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ MÁA ṢIṢẸ́ JÈHÓFÀ TỌKÀNTỌKÀN, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwòrán látinú fídíò “Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.” Thomas rí i pé Jason kọ̀ láti gba ẹ̀gúnjẹ níbi iṣẹ́.

    Kí nìdí tí Jason ò fi gba ẹ̀gúnjẹ?

  • Àwòrán látinú fídíò “Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.” Jason ń da ìdọ̀tí dànù níbi iṣẹ́.

    Báwo la ṣe lè fi Kólósè 3:23 sílò?

  • Àwòrán látinú fídíò “Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.” Jason ń kọ́ Thomas lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

    Báwo ni ìwà rere Jason ṣe ran Thomas lọ́wọ́?

  • Àwòrán látinú fídíò “Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.” Jason àti Thomas tètè kúrò níbi iṣẹ́ kí wọ́n lè lọ sípàdé.

    Máa fi Jèhófà sọ́kàn nínú gbogbo ohun tó o bá ń ṣe

    Báwo la ṣe lè fi Mátíù 6:22 sílò?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́