Dèbórà ń sọ fún Bárákì pé kó ran àwọn èèyàn Ọlọ́run lọ́wọ́
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jèhófà Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Là Nípasẹ̀ Àwọn Obìnrin Méjì
Ọ̀tá tó lágbára fòòró ẹ̀mí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Ond 4:3; 5:6-8; w15 8/1 12 ¶6)
Jèhófà yan Dèbórà pé kó ran àwọn èèyàn òun lọ́wọ́ (Ond 4:4-7; 5:7; w15 8/1 13 ¶1; wo àwòrán iwájú ìwé)
Jèhófà mú kí Jáẹ́lì pa Sísérà (Ond 4:16, 17, 21; w15 8/1 15 ¶2)
Kí la rí kọ́ nínú ìtàn yìí nípa ojú tí Jèhófà fi ń wo àwọn obìnrin?