ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”
Jèhófà sọ fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé wọn ò gbọ́dọ̀ fẹ́ ẹni tí ò sin òun (Di 7:3; w12 7/1 29 ¶2)
Jèhófà ò fẹ́ káwọn ìránṣẹ́ òun jìyà, kò sì fẹ́ kí wọ́n ní ẹ̀dùn ọkàn (Di 7:4; w15 3/15 30-31)
Ohun tí Jèhófà fẹ́ ká ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìgbéyàwó kò tíì yí pa dà (1Kọ 7:39; 2Kọ 6:14; w15 8/15 26 ¶12)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Àǹfààní wo ni màá rí tí mo bá fẹ́ “kìkì nínú Olúwa”?’