ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 12
  • Jèhófà Máa Ń Gba Tiwa Rò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń Gba Tiwa Rò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Tá A Lè Kọ́ Lára Sámúẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • “Mo Ta Kò Ó Lójúkojú”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 12
Àwòrán: 1. Sámúẹ́lì ń fetí sílẹ̀ bí Jèhófà ṣe ń bá a sọ̀rọ̀. 2. Sámúẹ́lì jíṣẹ́ tí Jèhófà fi rán an sí Élì.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Gba Tiwa Rò

Sámúẹ́lì rò pé Élì ló ń pe òun (1Sa 3:4-7; w18.09 24 ¶3)

Jèhófà jẹ́ kó ṣe kedere pé òun lòun ń pe Sámúẹ́lì (1Sa 3:8, 9)

Jèhófà gba ti Sámúẹ́lì tó jẹ́ ọ̀dọ́ rò (1Sa 3:15-18; w18.09 24 ¶4)

BI ARA Ẹ PÉ: ‘Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà fi hàn pé mo gba tàwọn ọ̀dọ́ àtàwọn àgbàlagbà rò? Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà fi hàn pé mo gba tàwọn míì rò tí mo bá wà nípàdé?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́