ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | GÁLÁTÍÀ 1-3
“Mo Ta Kò Ó Lójúkojú”
Báwo ni ìtàn yìí ṣe kọ́ wa láwọn ẹ̀kọ́ tó wà nísàlẹ̀ yìí?
A gbọ́dọ̀ jẹ́ onígboyà.—w18.03 31-32 ¶16
Ìbẹ̀rù èèyàn jẹ́ ìdẹkùn.—it-2 587 ¶3
Àwọn èèyàn Jèhófà kì í ṣe ẹni pípé, títí kan àwọn tó ń mú ipò iwájú.—w10 6/15 17-18 ¶12
A gbọ́dọ̀ máa gbìyànjú ní gbogbo ìgbà ká lè fa ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà tu kúrò ní ọkàn wa.—w18.08 9 ¶5