ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 March ojú ìwé 2
  • Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Sọ́ọ̀lù Nírẹ̀lẹ̀, Ó Sì Mọ̀wọ̀n Ara Ẹ̀ Níbẹ̀rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìkùgbù Máa Ń fa Àbùkù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • ‘Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 March ojú ìwé 2
Ọba Sọ́ọ̀lù kọjá àyè ẹ̀ bó ṣe fi ẹran rúbọ lórí pẹpẹ kan.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù

Ọba Sọ́ọ̀lù bá ara ẹ̀ nínú ipò tó le gan-an (1Sa 13:5-7)

Dípò kí Sọ́ọ̀lù mọ̀wọ̀n ara ẹ̀ kó sì tẹ̀ lé ìtọ́ni Jèhófà, ṣe ló kọjá àyè ẹ̀ (1Sa 13:8, 9; w00 8/1 13 ¶17)

Jèhófà bá Sọ́ọ̀lù wí (1Sa 13:13, 14; w07 6/15 27 ¶8)

Tí ẹnì kan bá ṣe ohun tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí láìgbàṣẹ, ó kọjá àyè ẹ̀ nìyẹn. Ẹni tó bá mọ̀wọ̀n ara ẹ̀ kò ní kọjá àyè ẹ̀. Àwọn ipò wo ló lè mú kẹ́nì kan kọjá àyè ẹ̀?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́