ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 March ojú ìwé 3
  • Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ta Ni Ọba Rẹ?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 March ojú ìwé 3
Ọba Sọ́ọ̀lù sọ fún ọmọ ogun Ísírẹ́lì kan tó mú idà lọ́wọ́ pé kó má pa Ágágì. Lọ́wọ́ ẹ̀yìn, ọmọ ogun míì ń bójú tó àwọn àgùntàn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ

Wòlíì Jèhófà fún Ọba Sọ́ọ̀lù ní ìtọ́ni tó ṣe pàtó (1Sa 15:3)

Sọ́ọ̀lù ò ṣègbọràn sí Jèhófà délẹ̀délẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í wá àwíjàre (1Sa 15:13-15)

Jèhófà kì í gba ìjọsìn àwọn tí kò bá ṣègbọràn sí i (1Sa 15:22, 23; w07 6/15 26 ¶4; it-2 521 ¶2)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo máa ń tètè tẹ̀ lé ìtọ́ni tí ètò Ọlọ́run bá fún wa, ṣé mo sì máa ń ṣe bẹ́ẹ̀ délẹ̀délẹ̀?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́