ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 8
  • Ṣé O Máa Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àṣìṣe Ẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé O Máa Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àṣìṣe Ẹ?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe tí Mo Bá Ṣàṣìṣe?
    Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè 10 Táwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè
  • Kí Ni Mo Lè Ṣe Nípa Àwọn Àṣìṣe Mi?
    Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé
  • Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Èéṣe Tí O Fi Níláti Gba Àṣìṣe?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 8
Arábìnrin kan ń ka Bíbélì, ó sì ń ronú nípa ohun tí Ádóníjà ṣe. Fọ́tò: 1. Ádóníjà gbá ìwo pẹpẹ mú. 2. Ádóníjà ń béèrè nǹkan lọ́wọ́ Bátí-ṣébà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé O Máa Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àṣìṣe Ẹ?

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àwọn Ọba Kìíní.]

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Ádóníjà dọ́gbọ́n wá bó ṣe máa di ọba, Sólómọ́nì ṣàánú ẹ̀ (1Ọb 1:5, 52, 53; it-2 987 ¶4)

Ádóníjà ò kẹ́kọ̀ọ́ látinú àṣìṣe ẹ̀, ó sì jìyà àbájáde ẹ̀ (1Ọb 2:15-17, 22, 23; it-1 49)

Ẹni tó gbọ́n máa ń kẹ́kọ̀ọ́ látinú àṣìṣe ẹ̀. Àmọ́, èyí tó dáa jù ni pé kéèyàn kẹ́kọ̀ọ́ látinú àṣìṣe àwọn míì.​—1Kọ 10:11.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́