ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 11
  • Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 11

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Fara Wé Bí Jèhófà Ṣe Ń Lo Ọlá Àṣẹ Rẹ̀

Jèhófà ni aláṣẹ tó ga jù lọ láyé àtọ̀run (1Ọb 22:19; it-2 21)

Jèhófà máa ń buyì kún àwọn tó wà lábẹ́ rẹ̀ (1Ọb 22:20-22; w21.02 4 ¶9)

Jèhófà bù kún iṣẹ́ tí áńgẹ́lì kan ṣe (1Ọb 22:23; it-2 245)

Bàbá kan ń ṣe ìjọsìn ìdílé pẹ̀lú ìyàwó àti ọmọbìnrin ẹ̀. Bàbá náà ń rẹ́rìn-ín músẹ́ bó ṣe ń wò ó tí ọmọbìnrin ẹ̀ ń fi ọ̀yàyà sọ̀rọ̀.

Ó ṣe pàtàkì káwọn alàgbà àtàwọn olórí ìdílé fara wé Jèhófà tó bá kan bí wọ́n ṣe ń lo ipò orí wọn. (Ef 6:4; 1Pe 3:7; 5:2, 3) Tí wọ́n bá ṣe bẹ́ẹ̀, àwọn tó wà lábẹ́ wọn máa láyọ̀, ara á sì tù wọ́n.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́