ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 12
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Òpó Méjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Òpó Méjì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • B8 Tẹ́ńpìlì Tí Sólómọ́nì Kọ́
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 12
Àwọn òpó bàbà méjì wà níbi àbáwọlé tẹ́ńpìlì.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tá A Rí Kọ́ Lára Òpó Méjì

Wọ́n kọ́ àwọn òpó ràgàjì méjì sí ibi àbáwọlé tẹ́ńpìlì náà (1Ọb 7:15, 16; w13 12/1 13 ¶3)

Wọ́n fún àwọn òpó náà ní orúkọ tó nítumọ̀ (1Ọb 7:21; it-1 348)

Táwọn èèyàn náà bá gbára lé Jèhófà, ó máa ràn wọ́n lọ́wọ́ láti “fìdí [tẹ́ńpìlì náà] múlẹ̀ gbọn-in” (1Ọb 7:21, àlàyé ìsàlẹ̀; Sm 127:1)

Jèhófà lè ti ràn wá lọ́wọ́ láti borí ọ̀pọ̀ ìṣòro ká lè wá sínú òtítọ́. Àmọ́, a gbọ́dọ̀ máa gbára lé e nìṣó tá a bá fẹ́ “dúró gbọn-in nínú ìgbàgbọ́.”​—1Kọ 16:13.

Fọ́tò: 1. Obìnrin kan tó wà nílé ìtajà gba ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì” lọ́wọ́ arábìnrin kan. 2. Obìnrin kan ń ronú bóyá kóun mu sìgá tàbí kóun má ṣe bẹ́ẹ̀ bó ṣe ń ka ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìjíròrò Látinú Bíbélì” nílé. 3. Ó ṣèrìbọmi.

BI ARA Ẹ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo gbára lé Jèhófà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́