ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 10
  • Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Dáfídì àti Sọ́ọ̀lù
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • ‘Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìdí Tí Dáfídì Fi Gbọ́dọ̀ Sá Lọ
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Sámúẹ́lì
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 10
Àwòrán: 1. Ọba Sọ́ọ̀lù ò mọ̀wọ̀n ara ẹ̀, ó sì rú ẹbọ lórí pẹpẹ. 2. Dáfídì kọ̀ láti mu omi tí ọ̀kan lára àwọn ọmọ ogun ẹ̀ gbé wá.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run

Jèhófà kọ Sọ́ọ̀lù lọ́ba torí ó ṣàìgbọràn (1Kr 10:13, 14)

Jèhófà yan Dáfídì dípò rẹ̀ (1Kr 11:3)

Dáfídì ò dà bíi Sọ́ọ̀lù, ó máa ń tẹ̀ lé àwọn òfin àti ìlànà Jèhófà (1Kr 11:15-19; w12 11/15 6 ¶12-13)

Ó máa ń wu Dáfídì láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run. (Sm 40:8) Àwa náà lè fi kọ́ra láti máa ṣe ohun tó tọ́ tá a bá ń fi ojú ti Jèhófà fi ń wo nǹkan wò ó.—Sm 25:4; w18.06 17 ¶5-6.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́