ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 12
  • A Máa Ṣàṣeyọrí Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìlànà Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • A Máa Ṣàṣeyọrí Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìlànà Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Ṣé Èèyàn Wúlò fún Ọlọ́run?”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Kí Ni Àpótí Májẹ̀mú?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 12
Ọba Dáfídì àtàwọn ọmọ Ísírẹ́lì míì ń kọrin, wọ́n sì ń jó bí àwọn ọmọ Léfì ṣe ń gbé àpótí májẹ̀mú.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

A Máa Ṣàṣeyọrí Tá A Bá Ń Tẹ̀ Lé Ìlànà Jèhófà

Dáfídì fẹ́ gbé àpótí májẹ̀mú pa dà sí Jerúsálẹ́mù (1Kr 13:3)

Kò ṣàṣeyọrí torí pé kò tẹ̀ lé ìlànà tó wà fún gbígbé àpótí náà (1Kr 15:13; w03 5/1 10-11)

Dáfídì ṣàṣeyọrí nígbà tó wà ìtọ́sọ́nà Jèhófà (1Kr 15:2; 16:11; w03 5/1 11 ¶13)

Jèhófà mọyì àwọn ohun rere tí à ń ṣe. Àmọ́, kí Jèhófà tó lè tẹ́wọ́ gba àwọn ohun tá à ń ṣe, a gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ìlànà rẹ̀. —Di 30:16.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́