ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 8
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àwọn Ẹranko
    Jí!—2015
  • Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I

Tí wọ́n bá rí ẹranko tó wà nínú wàhálà, wọn ò gbọ́dọ̀ pa á tì (Di 22:4; it-1 375-376)

Wọn ò gbọ́dọ̀ hùwà ìkà sí ẹyẹ tó lọ́mọ (Di 22:6, 7; it-1 621 ¶1)

Wọn ò gbọ́dọ̀ fi ẹranko tó yàtọ̀ síra túlẹ̀ pa pọ̀ (Di 22:10; w03 10/15 32 ¶1-2)

Wọ́n so màlúù àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ pa pọ̀. Ohun tí wọ́n fi so wọ́n wọ́ torí pé àwọn ẹran yẹn ò ga tó ra.

Jèhófà fẹ́ ká máa bójú tó àwọn ẹranko, torí wọ́n ṣe pàtàkì sí i. A ò gbọ́dọ̀ hùwà ìkà sí àwọn ẹranko tàbí ká kàn máa pa wọ́n ṣeré.​—Owe 12:10.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́