ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 15
  • Ẹ Fi Ìlànà Bíbélì Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọn Lè Ṣàṣeyọrí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ Fi Ìlànà Bíbélì Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọn Lè Ṣàṣeyọrí
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Fi Hàn Pé O Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́ Kó O Lè Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ẹ̀yin Òbí​—⁠Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Múnú Jèhófà Dùn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O sì Gbà Pé Àwọn Nǹkan Kan Wà Tó Ò Mọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 15
Àwòrán: Àwọn òbí kan ń kọ́ ọmọbìnrin wọn bó ṣe ń dàgbà. 1. Ìyá náà ń lo ìwé “Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà” láti kọ́ ọmọbìnrin rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́. 2. Bí ọmọbìnrin náà ṣe ń dàgbà sí i, bàbá rẹ̀ ń kọ́ ọ bó ṣe máa múra ìkẹ́kọ̀ọ́ “Ilé Ìṣọ́” sílẹ̀. 3. Ní báyìí tí ọmọbìnrin náà ti dàgbà, ó ń wàásù fún obìnrin kan lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ilé-dé-ilé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ Fi Ìlànà Bíbélì Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọn Lè Ṣàṣeyọrí

Àwọn òbí Kristẹni fẹ́ kí àwọn ọmọ wọn láyọ̀ kí wọ́n sì gbádùn iṣẹ́ ìsìn wọn sí Jèhófà. Àwọn òbí lè ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ láti ṣàṣeyọrí tí wọ́n bá ń fi àwọn ìlànà Bíbélì kọ́ wọn.—Owe 22:6.

  • Jẹ́ kó rọrùn fún àwọn ọmọ rẹ láti bá ẹ sọ̀rọ̀.—Jem 1:19

  • Fi àpẹẹrẹ tó dáa lé lẹ̀ fún wọn.—Di 6:6

  • Máa kópa nínú ìjọsìn Jèhófà déédéé.—Ef 6:4

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ KỌ́ ILÉ TÓ MÁA WÀ PẸ́ TÍTÍ—Ẹ TỌ́ ÀWỌN ỌMỌ YÍN ‘NÍ Ọ̀NÀ TÍ WỌN YÓÒ TỌ̀,’ KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Báwo lẹ̀yin òbí ṣe lè fòye bá àwọn ọmọ yín lò?

  • Báwo lẹ̀yin òbí ṣe lè fi ìlànà tó wà ní Jémíìsì 1:19 sílò?

  • Kí lẹ̀yin òbí lè ṣe tí ìṣòro bá yọjú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́