ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 7
  • “Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 7

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ”

Amasááyà háyà àwọn ọmọ ogun nígbà tó fẹ́ bá àwọn ọ̀tá Ọlọ́run jà (2Kr 25:5, 6)

Èèyàn Ọlọ́run kan sọ fún Amasááyà pé kó ní káwọn ọmọ ogun tó háyà náà pa dà sílé (2Kr 25:7, 8; it-1 1266 ¶6)

Jèhófà lè fún Amasááyà ní ọrọ̀ tó pọ̀ ju ohun tó pàdánù lọ (2Kr 25:9, 10)

Àwòrán: Arábìnrin kan ń ronú nípa ohun ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ méjì tó lè fi ìgbésí ayé ẹ̀ ṣe. 1. Òun àti ọ̀rẹ́ ẹ̀ tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà jọ ń lọ sí kíláàsì; òun àti arábìnrin àgbàlagbà kan jọ ń ṣiṣẹ́ lóde ìwàásù. 2. Ó ṣiṣẹ́ dalẹ́ níbiṣẹ́; ó ń fayọ̀ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn tó ń kọ́lé ètò Ọlọ́run. 3. Ó ń ṣe àfihàn kan níbiṣẹ́; ó ń kọ obìnrin kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

BI ARA RẸ PÉ: ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè yááfì kí n lè ṣe púpọ̀ sí i fún Jèhófà? Àwọn àǹfààní wo ni mo máa rí tí mo bá ṣe bẹ́ẹ̀?’​—Mal 3:10; w21.08 30 ¶16.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́