ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 12
  • Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Máa Ń San Àwọn Tó Bá Nígboyà Lẹ́san
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jòsáyà Ní Àwọn Ọ̀rẹ́ Rere
    Kọ́ Ọmọ Rẹ
  • “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jèhófà Ọlọ́run Yín”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 12
Ìdààmú bá Ọba Jòsáyà, ó sì fa aṣọ ẹ̀ ya.

Jòsáyà fa aṣọ ẹ̀ ya nígbà tó gbọ́ ohun tí ìwé òfin Jèhófà sọ

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?

Jòsáyà fara balẹ̀ tẹ́tí sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (2Kr 34:18, 19)

Ó ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kó lè lóye ohun tó gbọ́ nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (2Kr 34:21; it-1 1157 ¶4; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ó ṣiṣẹ́ lórí ohun tó gbọ́ (2Kr 34:33; w09 6/15 10 ¶20)

Lẹ́yìn tí arákùnrin kan ka Bíbélì, ó dá àwọn géèmù ìwà ipá tó ní nù.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo máa ń tètè ṣiṣẹ́ lórí ohun tí mo kà nípa Jèhófà nínú Bíbélì Ọ̀rọ̀ rẹ̀?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́