ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 May ojú ìwé 14
  • Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Ẹ Má Ṣe Dí Iṣẹ́ Náà Lọ́wọ́’
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 May ojú ìwé 14

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sírà.]

Jèhófà ta ẹ̀mí Ọba Kírúsì jí láti dá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ (Ẹsr 1:1-3; w22.03 14 ¶1)

Jèhófà ta ẹ̀mí àwọn èèyàn ẹ̀ jí kí wọ́n lè tún tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù kọ́ (Ẹsr 1:5; w17.10 26 ¶2)

Arákùnrin kan àti ìyàwó ẹ̀ tó ṣèṣe gan-an wà ní ilé ìwòsàn, arákùnrin míì sì ń fi Bíbélì tù wọ́n nínú.

Tó o bá yọ̀ǹda ara ẹ fún iṣẹ́ Jèhófà, ó máa lò ẹ́ láti mú ìfẹ́ ẹ̀ ṣẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́