ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 5
  • Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Òótọ́ Làwọn Ìtàn Bíbélì, Kì Í Ṣe Àròsọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kan fẹ́ àwọn obìnrin tó jẹ́ abọ̀rìṣà (Ẹsr 9:1, 2; w06 1/15 20 ¶1)

Wọn ò ṣègbọràn sí òfin tí Jèhófà fún wọn (Ẹsr 9:10-12)

Àwọn àti ìdílé wọn jìyà gan-an nítorí àìgbọràn wọn (Ẹsr 10:10, 11, 44)

Arábìnrin kan tó fẹ́ ẹni tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti bímọ, ó sì ń ronú nípa bí ìgbésí ayé ẹ̀ ṣe rí nígbà tó ṣì ń ṣe dáadáa nínú ìjọ. Àwọn sìgá àmukù wà lórí tábìlì. Ọkọ ẹ̀ tó sì ti mutí yó sùn sórí àga.

Ire wa ni gbogbo àṣẹ Jèhófà wà fún. (w09 10/1 10 ¶6) Tá a bá jẹ́ onígbọràn, a ò ní jìyà bíi táwọn aláìgbọràn, a sì máa gbádùn ìbùkún Jèhófà títí láé.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn ìṣòro wo ni mi ò bá ti kó sí ká sọ pé mi ò ṣègbọràn sí Jèhófà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́