ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 2
  • ‘Ẹ Má Ṣe Dí Iṣẹ́ Náà Lọ́wọ́’

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • ‘Ẹ Má Ṣe Dí Iṣẹ́ Náà Lọ́wọ́’
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022
  • Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìgbà Wo Ló Yẹ Ká Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

‘Ẹ Má Ṣe Dí Iṣẹ́ Náà Lọ́wọ́’

Jéṣúà (tàbí Jóṣúà) Àlùfáà Àgbà àti Gómínà Serubábélì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ tẹ́ńpìlì láìka àṣẹ ọba tí wọ́n fi fòfin de iṣẹ́ náà sí (Ẹsr 5:1, 2; w22.03 18 ¶13)

Nígbà táwọn alátakò béèrè ẹni tó fún wọn láṣẹ láti kọ́ ilé náà, àwọn Júù tọ́ka sí àṣẹ tí Ọba Kírúsì pa (Ẹsr 5:3, 17; w86 6/1 29, àpótí ¶2-3)

Ọba náà ṣèwádìí, ó sì rí i pé lóòótọ́ ni Ọba Kírúsì fún wọn láṣẹ láti kọ́ ilé náà, ó wá pàṣẹ fáwọn alátakò náà pé wọn ò gbọ́dọ̀ dí iṣẹ́ náà lọ́wọ́ (Ẹsr 6:7, 8; w22.03 15 ¶7)

Arábìnrin kan ń wo èto tẹ́lifíṣọ̀n JW, ó wá ń fojú inú wo bí Serubábélì àti Jéṣúà Àlùfáà Àgbà ṣe ń darí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń tún tẹ́ńpìlì kọ́.

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Báwo ni ìtàn Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká rí i pé ó yẹ ká máa tẹ̀ lé ìtọ́ni àwọn tí Jèhófà yàn láti máa bójú tó wa, kódà tí ohun tí wọ́n ní ká ṣe ò bá fi bẹ́ẹ̀ yé wa?​—w22.03 19 ¶16.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́