ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 7
  • Ṣé Ó Máa Ń Yá Ẹ Lára Láti Ṣe Iṣẹ́ Tó Dà Bíi Pé Ó Rẹlẹ̀?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ó Máa Ń Yá Ẹ Lára Láti Ṣe Iṣẹ́ Tó Dà Bíi Pé Ó Rẹlẹ̀?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fayọ̀ Ṣe Ohun Tágbára Ẹ Gbé Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 7
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ́kùnrin àti lóbìnrin ń jára mọ́ iṣẹ́ kíkọ́ ògiri Jerúsálẹ́mù.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé Ó Máa Ń Yá Ẹ Lára Láti Ṣe Iṣẹ́ Tó Dà Bíi Pé Ó Rẹlẹ̀?

Àlùfáà àgbà àtàwọn arákùnrin rẹ̀ ò jọ ara wọn lójú, wọn ò sì ronú pé kì í ṣe irú àwọn ló yẹ kí wọ́n bá nídìí iṣẹ́ kíkọ́ ògiri Jerúsálẹ́mù (Ne 3:1)

Àwọn olókìkí kan láàárín wọn kọ̀ láti “rẹ ara wọn sílẹ̀,” wọn ò sì lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ náà (Ne 3:5; w06 2/1 10 ¶1)

Àwọn obìnrin tó bẹ̀rù Ọlọ́run fínnúfíndọ̀ yọ̀ǹda ara wọn láti ṣe iṣẹ́ tó lágbára, tó sì léwu yìí (Ne 3:12; w19.10 23 ¶11)

Ọ̀pọ̀ iṣẹ́ tá à ń ṣe nínú ìjọ ló jẹ́ iṣẹ́ alágbára tàbí iṣẹ́ tó dà bíi pé ó rẹlẹ̀, àwọn èèyàn sì lè má rí wa nígbà tá a bá ń ṣe é.​—w04 8/1 18 ¶16.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ó máa ń yá mi lára láti ṣe irú àwọn iṣẹ́ yìí?’​—1Kọ 9:23.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́