ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 January ojú ìwé 13
  • Máa Fayọ̀ Ṣe Ohun Tágbára Ẹ Gbé Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fayọ̀ Ṣe Ohun Tágbára Ẹ Gbé Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
  • Jẹ́ Kó Máa Wù Ẹ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣàṣeyọrí
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ṣé Ó Máa Ń Yá Ẹ Lára Láti Ṣe Iṣẹ́ Tó Dà Bíi Pé Ó Rẹlẹ̀?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 January ojú ìwé 13

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fayọ̀ Ṣe Ohun Tágbára Ẹ Gbé Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà

Ó wu Dáfídì pé kó kọ́ tẹ́ńpìlì kan tó rẹwà fún Jèhófà (1Kr 17:1, 2; w06 7/15 19 ¶1)

Jèhófà sọ pé Dáfídì kọ́ ló máa kọ́ tẹ́ńpìlì náà (1Kr 17:4)

Dáfídì pọkàn pọ̀ sórí iṣẹ́ tí Jèhófà fún un (1Kr 17:7; 18:14)

Àwòrán: 1. Ìrẹ̀wẹ̀sì bá arákùnrin kan tó jókòó sórí kẹ̀kẹ́ arọ tó sì ń fi táǹkì afẹ́fẹ́ ọ́síjìn mí. 2. Inú arákùnrin náà ń dùn bó ṣe ń wàásù fún ọkùnrin kan tó wá síbi àtẹ ìwé.

Tí ọjọ́ ogbó, àìlera tàbí àwọn nǹkan míì ò bá jẹ́ kó o lè bójú tó iṣẹ́ kan bó o ṣe fẹ́, ohun tó dáa jù ní pé kó o pọkàn pọ̀ sórí ohun tí agbára ẹ gbé.—Iṣe 18:5; w21.08 22-23 ¶11.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́