ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 12
  • Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Iwọ Ha Ń Tọ Jehofa Lẹhin Lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́ Bi?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Àwọn Amí Méjìlá
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ẹ̀kọ́ Bíbélì
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 12

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà

Àtikékeré ni Kélẹ́bù ti ń fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀ lé Jèhófà (Joṣ 14:7, 8)

Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún, Kélẹ́bù ṣì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà tó fẹ́ ṣe iṣẹ́ kan tó nira láti bójú tó (Joṣ 14:10-12; w04 12/1 12 ¶2)

Jèhófà bù kún Kélẹ́bù torí pé ó fi tọkàntọkàn sìn ín (Joṣ 14:13, 14; w06 10/1 18 ¶11)

Àwòrán: Arábìnrin àgbàlagbà kan ń fòótọ́ sin Jèhófà láìka ipò tó wà sí. 1. Ó fi ọ̀pá tilẹ̀ bó ṣe jókòó tó sì ń gbàdúrà. 2. Ó wà níbi ìpàtẹ ìwé pẹ̀lú ọ̀dọ́bìnrin kan. 3. Ó ń fi fọ́tò han àwọn ọmọ inú ìjọ rẹ̀ tó wá kí i nílé. 4. Ó ń rẹ́rìn-ín, ọkàn ẹ̀ sì balẹ̀.

Bí Kélẹ́bù ṣe ń tẹ̀ lé ìtọ́ni Jèhófà, tí Jèhófà sì ń bù kún un, ìyẹn ń mú kí ìgbàgbọ́ rẹ̀ túbọ̀ lágbára. Báwa náà ṣe ń rí i tí Jèhófà ń dáhùn àdúrà wa, tó sì ń tọ́ wa sọ́nà, ìgbàgbọ́ wa á máa lágbára sí i, àá sì máa bá a lọ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà.​—1Jo 5:14, 15.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́