ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 10
  • “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìdùnnú-Ayọ̀ Jehofa Ni Odi-Agbára Wa
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1995
  • Ìdùnnú Jèhófà
    Kọrin sí Jèhófà
  • Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • “Ìdùnnú Jèhófà”
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 10
Ẹ́sírà mú àkájọ ìwé kan dání, ó sì ń yin Jèhófà níwájú àwọn èèyàn náà.

Ẹ́sírà ń ka Òfin Ọlọ́run fún àwọn èèyàn náà, ó sì ń yin Jèhófà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”

Àwọn èèyàn náà kóra jọ láti gbọ́ bí Ẹ́sírà ṣe máa ka Òfin Ọlọ́run (Ne 8:1, 2; w13 10/15 21 ¶2; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ọjọ́ ayọ̀ lọjọ́ náà jẹ́ fáwọn èèyàn Jèhófà, kì í ṣe àsìkò láti máa kárí sọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti dá sẹ́yìn (Ne 8:9, 11, 12)

Ìdùnnú Jèhófà jẹ́ ibi ààbò fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ (Ne 8:10; w07 7/15 22 ¶9-10)

Inú tọkọtaya kan tí ò tíì dàgbà ń dùn bí wọ́n ṣe ń bá tọkọtaya àgbàlagbà kan sọ̀rọ̀ ní àpéjọ agbègbè kan.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Láìka àwọn ìṣòro tí mò ń dojú kọ sí, àwọn nǹkan pàtó wo ni Jèhófà ti ṣe tó ń fún mi láyọ̀?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́