ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 4
  • Má Ṣe Sọ̀rọ̀ Bíi Élífásì Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Ṣe Sọ̀rọ̀ Bíi Élífásì Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Má Ṣe Fàyè Gba Èrò Òdì!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • A San Èrè fún Ìwà Títọ́ Jóòbù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1998
  • Inú Jèhófà Máa Ń Dùn Tá A Bá Gbàdúrà Fáwọn Ẹlòmíì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Rere Tó Ń Gbéni Ró Tó sì Ń Fúnni Lókun
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Sọ̀rọ̀ Bí Élífásì Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú

Élífásì sọ fún Jóòbù pé kò sí ohun táwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run lè ṣe tó máa dáa lójú Ọlọ́run (Job 15:​14-16; w05 9/15 26 ¶4-5)

Élífásì ń dọ́gbọ́n sọ pé torí pé èèyàn burúkú ni Jóòbù ló ṣe ń jìyà (Job 15:20)

Ó dájú pé ọ̀rọ̀ Élífásì ò tu Jóòbù nínú (Job 16:​1, 2)

Élífásì nàka sí Jóòbù tí eéwo bò látorí dé ẹsẹ̀, ó sì ń dá a lẹ́bi, bẹ́ẹ̀ làwọn olùtùnú èké méjì tó kù ń wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀.

Irọ́ ni ohun tí Élífásì sọ nípa Jóòbù. Ìdí ni pé Jèhófà mọyì gbogbo ohun tá à ń ṣe láti sìn ín. (Sm 149:4) Ohun kan ni pé àwọn olódodo máa kojú ọ̀pọ̀ ìṣòro nínú ayé yìí.—Sm 34:19.

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Báwo la ṣe lè “máa sọ̀rọ̀ ìtùnú fún àwọn tó sorí kọ́”?—1Tẹ 5:14; w15 2/15 9 ¶16.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́