ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 December ojú ìwé 6
  • “Wò Ó! Mò Ń Sọ Ohun Gbogbo di Tuntun”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Wò Ó! Mò Ń Sọ Ohun Gbogbo di Tuntun”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọ̀run Tuntun àti Ayé Tuntun Máa Mú Ká Láyọ̀ Tó Kọ Yọyọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • ‘Àwọn Ohun Àtijọ́ Ni A Kì Yóò Mú Wá sí Ìrántí’
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ìfihàn 21:1—“Ọ̀run Tuntun Kan àti Ayé Tuntun Kan”
    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì
  • Ayé Tuntun Kan Tí Ọlọ́run Ṣèlérí
    Ẹ Máa Ṣọ́nà!
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 December ojú ìwé 6
Òkúta jásípérì ni wọ́n fi ṣe ògiri Jerúsálẹ́mù Tuntun, ìlú náà sì jẹ́ ògidì wúrà bíi gíláàsì tó mọ́ kedere

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌFIHÀN 20-22

“Wò Ó! Mò Ń Sọ Ohun Gbogbo di Tuntun”

21:1-5

Jèhófà ṣèlérí pé òun máa sọ ohun gbogbo di tuntun.

  • “Ọ̀run tuntun”: Ìjọba tuntun kan tó máa mú kí òdodo gbilẹ̀ lórí ilẹ̀ ayé

  • “Ayé tuntun”: Àwọn èèyàn tó fi ara wọn sábẹ́ ìṣàkóso Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń fi àwọn ìlànà rẹ̀ sílò nígbèésí ayé wọn

  • “Ohun gbogbo di tuntun”: Gbogbo ẹ̀dùn ọkàn, ìrora àtàwọn nǹkan míì tó ń fa ìbànújẹ́ máa pòórá, ojoojúmọ́ sì ni ìgbésí ayé wa á máa dùn bí oyin

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́