ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sn orin 11
  • Mímú Ọkàn Jèhófà Yọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Mímú Ọkàn Jèhófà Yọ̀
  • Kọrin sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bá A Ṣe Lè Mú Ọkàn Jèhófà Yọ̀
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Báwo Ló Ṣe Máa Ń Rí Lára Rẹ?
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Báwo Ló Ṣe Rí Lára Rẹ?
    Kọrin sí Jèhófà—Àwọn Orin Tuntun
  • “Máa Wádìí Dájú Àwọn Ohun Tí Ó Ṣe Pàtàkì Jù”
    Kọrin sí Jèhófà
Àwọn Míì
Kọrin sí Jèhófà
sn orin 11

Orin 11

Mímú Ọkàn Jèhófà Yọ̀

Bíi Ti Orí Ìwé

(Òwe 27:11)

1. Ọlọ́run àwa ti jẹ́jẹ̀ẹ́;

Láti fọgbọ́n ṣe iṣẹ́ rẹ.

Ìgbà náà làwa lè nípìn-ín

Nínú mímú ọkàn rẹ yọ̀.

2. Ẹrú rẹ olóòótọ́ láyé,

Ńkéde ọlá ńlá rẹ fáyé.

Ó ńbọ́ wa lákòókò tó yẹ,

Ká lókun láti ṣèfẹ́ rẹ.

3. Fún wa ní ẹ̀mí mímọ́ rẹ,

Ká lè máa rin ọ̀nà òótọ́,

Ká máa sèso fún ìyìn rẹ,

Ká lè mọ́kàn rẹ yọ̀ láéláé.

(Tún wo Mát. 24:45-47; Lúùkù 11:13; 22:42.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́