ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 February ojú ìwé 4
  • Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀?—Apá 1
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀?—APÁ 2
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
  • Bí A Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tá A Gbà Gbọ́ Nípa Ọdún 1914
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2013
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 February ojú ìwé 4

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní làwọn ọ̀dọ́ ní nínú ètò Jèhófà. Wo fídíò Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ kó o lè rí bí Cameron ṣe fi ọgbọ́n lo ìgbà ọ̀dọ́ rẹ̀. Lẹ́yìn náà, dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí. (Lọ sórí ìkànnì jw.org/yo, wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.)

Cameron ń fi okùn wọn bí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ṣe jìnnà sí Màláwì to lórí máàpù
  • Kí ni ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ nígbèésí ayé Cameron?

  • Ìgbà wo ló ti pinnu láti ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀, báwo ló sì ṣe ṣeé?

  • Báwo ló ṣe múra sílẹ̀ kó lè lọ sìn lórílẹ̀-èdè tí wọ́n ti nílò àwọn oníwàásù Ìjọba Ọlọ́run?

    Cameron ń ṣàlàyé ẹsẹ Bíbélì fún obìnrin kan ní Màláwì
  • Àwọn nǹkan wo ni Cameron fara dà lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ lórílẹ̀-èdè tó lọ?

  • Kí nìdí tó fi máa ṣàǹfààní láti sin Jèhófà níbi tí a kò tíì ṣiṣẹ́ sìn rí?

  • Àwọn ìbùkún wo ni Cameron rí lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀?

    Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Màláwì ń juwọ́ sí wa
  • Kí nìdí tí ṣíṣe iṣẹ́ ìsìn Jèhófà fi jẹ́ ọ̀nà ìgbésí ayé tó dára jù lọ?

  • Àwọn àǹfààní iṣẹ́ ìsìn míì wo làwọn ọ̀dọ́ lè ní nínú ètò Jèhófà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́